Máàkù 10:51-52 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

51. Jésù béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé, “Kí ni ìwọ fẹ́ kí èmi kí ó ṣe fún ọ?”Afọ́jú náà dáhùn pé, “Rábì, jẹ́ kí èmi ki o ríran.”

52. Jésù wí fún un pé, “Má a lọ, ìgbàgbọ́ rẹ ti mú ọ láradá.” Lẹ́ṣẹ̀kẹṣẹ̀, ọkùnrin afọ́jú náà ríran ó sì ń tẹ̀lé Jésù lọ ní ọ̀nà.

Máàkù 10