Máàkù 10:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n bẹ̀bẹ̀ pé, “Jẹ́ kí ọ̀kan nínú wa jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ àti ẹnikejì ní ọwọ́ òsì nínú ògo rẹ!”

Máàkù 10

Máàkù 10:33-40