Máàkù 1:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jòhánù sì wọ ẹ̀wù tí a fi irun ràkúnmí hun. Ó sì lo ìgbànú awọ. Eṣú àti oyin ìgàn sì ni oúnjẹ rẹ̀.

Máàkù 1

Máàkù 1:2-8