Máàkù 1:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jésù sì dáhùn wí pé, “Ẹ jẹ́ kí a lọ sí àwọn ìlú mìíràn, kí ń lè wàásù níbẹ̀ pẹ̀lú. Nítorí èyí ni èmi sá à ṣe wá.”

Máàkù 1

Máàkù 1:30-41