Máàkù 1:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Ó sì ti rìn ṣíwájú díẹ̀, ní etí òkun, Ó rí Jákọ́bù àti Jòhánù, àwọn ọmọ Sébédè nínú ọkọ̀ wọ́n ń tún àwọ̀n wọn ṣe.

Máàkù 1

Máàkù 1:15-21