Máàkù 1:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohùn kan sì ti ọ̀run wá wí pé, “Ìwọ ni àyànfẹ́ Ọmọ mi, ìwọ ni ẹni tí inú mi dùn sí gidigidi.”

Máàkù 1

Máàkù 1:5-15