Lúùkù 7:49-50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

49. Àwọn tí ó bá a jókòó jẹun sì bẹ̀rẹ̀ síí rò nínú ara wọn pé, “Ta ni èyí tí ń dárí ẹ̀ṣẹ̀ ji ni pẹ̀lú?”

50. Ó sì dáhùn wí fún obìnrin náà pé, “Ìgbàgbọ́ rẹ gbà ọ́ là; má a lọ ní àlààáfíà.”

Lúùkù 7