Lúùkù 7:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ijọ́ kejì, ó lọ sí ìlú kan tí a ń pè ní Náínì: àwọn púpọ̀ nínú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sì ń bá a lọ àti ọ̀pọ̀ ìjọ ènìyàn.

Lúùkù 7

Lúùkù 7:2-14