Lúùkù 5:37-39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

37. Àti wí pé, kò sí ẹni tí ó lè dá otí wáìnì sínú ògbólógbò awọ, tí ó bá ṣe èyí, wáìnì tuntun yóò fa awọ náà ya, wáìnì náà yóò dànù awo náà a sí.

38. Nítorí náà, ó tọ́ kí á da wáìnì tuntun sínú awọ tuntun.

39. Kò sì ẹni tí yóò fẹ́ láti mu wáìnì tuntun lẹ́yìn tí ó bá ti mu ogbólógbò tán, nítorí yóò wí pé ‘èyí tí ó jẹ́ ògbólógbò dára jù.’ ”

Lúùkù 5