Lúùkù 4:43-44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

43. Ṣùgbọ́n ó sì wí fún wọn pé, “Èmi kò lè ṣàì má wàásù ìyìnrere ti ìjọba Ọlọ́run fún àwọn ìlú mìíràn pẹ̀lú: nítorí náà ni a sá ṣe rán mi.”

44. Ó sì ń wàásù nínú sínágọ́gù ti Jùdíà.

Lúùkù 4