Lúùkù 4:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì sọ̀kalẹ̀ wá sí Kápánáúmù, ìlú kan ní Gálílì, ó sì ń kọ́ wọn ní ọjọ́ ìsinmi.

Lúùkù 4

Lúùkù 4:22-33