Lúùkù 3:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jòhánù lo oríìṣíríṣìí ọ̀rọ̀ púpọ̀ láti gba àwọn ènìyàn níyànjú àti láti wàásù ìhìnrere fún wọn.

Lúùkù 3

Lúùkù 3:11-21