Lúùkù 23:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sì kíyèsí i, ọkùnrin kan tí a ń pè ní Jóṣẹ́fù, láti ìlú àwọn Júù kan tí ń jẹ́ Arimatíyà. Ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ọmọ ìgbìmọ̀, ènìyàn rere, àti olóòótọ́.

Lúùkù 23

Lúùkù 23:44-56