Lúùkù 23:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ọ̀kan nínú àwọn arúfin tí a gbé kọ́ ń fi ṣe ẹlẹ́yà wí pé, “Bí ìwọ bá ṣe Kírísítì, gba ara rẹ àti àwa là.”

Lúùkù 23

Lúùkù 23:32-40