Lúùkù 23:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti Hẹ́rọ́dù pẹ̀lú; ó sá rán an padà tọ̀ wá wá; sì kíyèsí i, ohun kan tí ó yẹ sí ikú ni a kò ṣe láti ọwọ́ rẹ̀.

Lúùkù 23

Lúùkù 23:6-20