Lúùkù 23:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pílátù àti Hẹ́rọdù di ọ̀rẹ́ ara wọn ní ijọ́ náà: nítorí látijọ́ ọ̀tá ara wọn ni wọ́n ti jẹ́ rí.

Lúùkù 23

Lúùkù 23:6-14