Lúùkù 23:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé dúró, wọ́n sì ń fí ẹ̀sùn kàn án gidigidi.

Lúùkù 23

Lúùkù 23:1-12