Lúùkù 22:69-71 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

69. Ṣùgbọ́n láti ìsinsinyìí lọ ni ọmọ-ènìyàn yóò jókòó lọ́wọ́ ọ̀tún agbára Ọlọ́run.”

70. Gbogbo wọn sì wí pé, “Ìwọ ha ṣe Ọmọ Ọlọ́run bí?”Ó sì wí fún wọn pé, “Ẹ̀yin wí pé, èmi ni.”

71. Wọ́n sì wí pé, “Ẹ̀rí wo ni àwa tún ń fẹ́ Àwa tìkarawa sáà ti gbọ́ lẹ́nu rẹ̀!”

Lúùkù 22