Lúùkù 22:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sàtánì sì wọ inú Júdásì, tí à ń pè ní Isíkáríọ́tù, ọ̀kan nínú àwọn méjìlá.

Lúùkù 22

Lúùkù 22:1-11