Lúùkù 21:17-19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

17. A ó sì kórìíra yín lọ́dọ̀ gbogbo ènìyàn nítorí orúkọ mi.

18. Ṣùgbọ́n irun orí yín kan kì yóò ṣègbé.

19. Nínú sùúrù yín ni ẹ̀yin ó jèrè ọkàn yín.

Lúùkù 21