Lúùkù 21:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ilẹ̀ríri ilẹ̀ ńlá yóò sì wà káàkiri, àti ìyàn àti àjàkálẹ̀-àrùn; ohun ẹ̀rù, àti àmì ńlá yóò sì ti ọ̀run wá.

Lúùkù 21

Lúùkù 21:2-16