Lúùkù 20:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ijọ́ kan, bí ó ti ń kọ́ àwọn ènìyàn ní tẹ́ḿpìlì tí ó sì ń wàásù ìyìn rere, àwọn olórí àlùfáà, àti àwọn alàgbà dìde sí i.

Lúùkù 20

Lúùkù 20:1-4