Lúùkù 2:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnìkan sì ń bẹ, Ánà wòlíì, ọmọbìnrin Fánúénì, ní ẹ̀yà Ásérì: ọjọ́ ogbó rẹ̀ pọ̀, ó ti bá ọkọ gbé ní ọdún méje láti ìgbà wúndíá rẹ̀ wá;

Lúùkù 2

Lúùkù 2:33-41