Lúùkù 19:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹnikẹ́ni bá sì bi yín pé, ‘Èéṣe tí ẹ̀yin fi ń tú u?’ Kí ẹ̀yin wí báyìí pé, ‘Olúwa ń fẹ́ lò ó.’ ”

Lúùkù 19

Lúùkù 19:21-32