Lúùkù 16:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ábúráhámù sì wí fún un pé, ‘Wọ́n ní Mósè àti àwọn wòlíì; kí wọn kí ó gbọ́ ti wọn.’

Lúùkù 16

Lúùkù 16:21-31