Lúùkù 15:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ó dìde, èmi ó sì tọ bàbá mi lọ, èmi ó sì wí fún un pé: Bàbá, èmí ti dẹ́sẹ̀ sí ọ̀run, àti níwájú rẹ;

Lúùkù 15

Lúùkù 15:16-21