Lúùkù 12:57-59 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

57. “Èé ha ti ṣe tí ẹ̀yin tìkárayín kò fi ro ohun tí ó tọ́?

58. Nígbà tí ìwọ bá bá ọ̀ta rẹ lọ sọ́dọ̀ onídàájọ́, rí i pé o bá a parí ọ̀rọ̀ ní ọ̀nà kí ó má baà fà ọ́ fún adájọ́, adájọ́ a fi ọ́ lé ẹ̀ṣọ́ lọ́wọ́, òun a sì tì ọ́ sínú túbú.

59. Kí èmi wí fún ọ, ìwọ kì yóò jáde kúrò níbẹ̀, títí ìwọ ó fi san ẹyọ owó kan tí ó bá kù!”

Lúùkù 12