Lúùkù 12:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ní ibi tí ìṣura yín gbé wà, níbẹ̀ ni ọkàn yín yóò gbé wà pẹ̀lú.

Lúùkù 12

Lúùkù 12:27-38