Lúùkù 1:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní oṣù kẹfà Ọlọ́run sì rán áńgẹ́lì Gébúríẹ́lì sí ìlú kan ní Gálílì, tí à ń pè ní Násárẹ́tì,

Lúùkù 1

Lúùkù 1:22-31