Léfítíkù 9:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ní ọjọ́ kẹjọ, Mósè pe Árónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì.

2. Ó sọ fún Árónì pé, “Mú akọ ọmọ màlúù kan wá fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ àti àgbò kan fún ẹbọ sísun, kí méjèèjì jẹ́ aláìlábùkù, kí o sì mú wọn wá sí iwájú Olúwa.

Léfítíkù 9