Léfítíkù 27:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹni tí ó ya ilẹ̀ sí mímọ́ bá fẹ́ rà á padà: kí ó san iye owó náà pẹ̀lú àfikún ìdá márùn-ún. Ilẹ̀ náà yóò sì di tirẹ̀.

Léfítíkù 27

Léfítíkù 27:14-24