Léfítíkù 25:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún àwọn ohun ọ̀sìn yín, àti àwọn ẹranko búburú ní ilẹ̀ yín. Ohunkóhun tí ilẹ̀ náà bá mú jáde ní ẹ lè jẹ.

Léfítíkù 25

Léfítíkù 25:5-14