Léfítíkù 25:49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àbúrò bàbá rẹ̀ ọkùnrin tàbí àbúrò rẹ̀ obìnrin tàbí ẹnikẹ́ni tí ó bá a tan nínú ìdílé rẹ̀ le è rà á padà: Bí ó bá sì ti là (Lówólọ́wọ́) ó lè ra ara rẹ̀ padà.

Léfítíkù 25

Léfítíkù 25:46-54