Léfítíkù 25:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Àwọn ẹrúkùnrin àti ẹrúbìnrin yín lè jẹ́ láti orílẹ̀ èdè tí ó yí yín ká: Ẹ lè ra àwọn ẹrú wọ̀nyí lọ́wọ́ wọn.

Léfítíkù 25

Léfítíkù 25:43-52