Léfítíkù 25:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Torí pé ìránṣẹ́ mi ni àwọn ará Ísírẹ́lì jẹ́. Ẹni tí mo mú jáde láti ilẹ̀ Éjíbítì wá, torí èyí ẹ kò gbọdọ̀ tà wọ́n lẹ́rú.

Léfítíkù 25

Léfítíkù 25:33-49