Léfítíkù 25:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ẹ ra ilẹ̀ lọ́wọ́ àwọn ènìyàn yín ní gẹ́gẹ́ bí iye owó tí ó kù kí ọdún ìdásílẹ̀ pé, kí òun náà sì ta ilẹ̀ fún yín gẹ́gẹ́ bí iye ọdún rẹ̀ tó kù láti kórè.

Léfítíkù 25

Léfítíkù 25:11-25