Léfítíkù 24:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Búrẹ́dì yìí ni kí ẹ gbé wá ṣíwájú Olúwa nígbàkugbà, lọ́sẹ̀ọ̀sẹ̀, nítorí tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gẹ́gẹ́ bí májẹ̀mú ayérayé.

Léfítíkù 24

Léfítíkù 24:5-17