Léfítíkù 24:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọkùnrin arábìnrin Ísírẹ́lì náà sọ̀rọ̀ òdì sí orúkọ Olúwa pẹ̀lú èpè: Wọ́n sì mú-un tọ Mósè wá. (Orúkọ ìyá rẹ̀ ní Selomiti, ọmọbìnrin Débírì, ará Dánì).

Léfítíkù 24

Léfítíkù 24:9-21