Léfítíkù 22:32-33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

32. Ẹ má ṣe ba orúkọ mímọ́ mi jẹ́. Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbọdọ̀ mọ̀ mí ní mímọ́. Èmi ni Olúwa tí ó sọ yín di mímọ́.

33. Tí ó sì mú yín jáde láti Éjíbítì wá láti jẹ́ Ọlọ́run yín. Èmi ni Olúwa.”

Léfítíkù 22