Léfítíkù 20:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Kí ẹ pa gbogbo àṣẹ àti òfin mi mọ́, kí ẹ sì máa ṣe wọ́n. Kí ilẹ̀ náà tí èmi ó fi fún yín láti máa gbé má baà pọ̀ yín jáde.

Léfítíkù 20

Léfítíkù 20:18-27