Léfítíkù 20:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Má ṣe bá arábìnrin bàbá tàbí ti ìyá rẹ lòpọ̀, nítorí o ti tú ìhòòhò ìbátan rẹ: Ẹ̀yin méjèèjì ni yóò ru ẹ̀bi yín.

Léfítíkù 20

Léfítíkù 20:12-23