Léfítíkù 19:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọdún karùn ún ni ẹ̀yin tó lè jẹ nínú èso igi náà, kí èso wọn ba à le máa pọ̀ sí i. Èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín.

Léfítíkù 19

Léfítíkù 19:17-28