Léfítíkù 16:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Árónì yóò sì mú ewúrẹ́ tí ìbò Ọlọ́run mú, yóò sì fi rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀.

Léfítíkù 16

Léfítíkù 16:5-12