Léfítíkù 16:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì ṣe ètùtù fún àgọ́ ìpàdé àti fún pẹpẹ: yóò sì ṣe ètùtù fún àlùfáà àti fún gbogbo àgbájọpọ̀ àwọn ènìyàn náà.

Léfítíkù 16

Léfítíkù 16:26-34