Léfítíkù 14:54-57 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

54. Àwọn wọ̀nyí ni ìlànà fún èyíkéyí àrùn àwọ̀ ara tí ó le è ràn ká (ẹ̀tẹ̀), fún làpálàpá,

55. fún ẹ̀tẹ̀ nínú aṣọ, tàbí ilé,

56. fún ìwú, fún èélá àti ibi ara dídán.

57. Láti mú kí a mọ̀ bóyá nǹkan mọ́ tàbí kò mọ́.Ìwọ̀nyí ni àwọn òfin fún àrùn àwọ̀ ara tí ó ń ràn ká àti ẹ̀tẹ̀.

Léfítíkù 14