Léfítíkù 13:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbáà ṣe títa tàbí híhun tí ó jẹ́ aṣọ funfun tàbí irun àgùtàn, bóyá àwọ̀ tàbí ohun tí a fi àwọ̀ ṣe.

Léfítíkù 13

Léfítíkù 13:43-53