Léfítíkù 13:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Alárùn ni ọkùnrin náà: kò sì mọ́, kí àlùfáà pe ẹni náà ní aláìmọ́ torí egbò tí ó wà ní orí rẹ̀.

Léfítíkù 13

Léfítíkù 13:38-51