Kólósè 4:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ jẹ́ kí ọ̀rọ̀ yín kí ó dàpọ̀ mọ́ oore-ọ̀fẹ́ nígbà gbogbo, èyí tí a fi iyọ̀ dùn, kí ẹ̀yin kí ó le mọ́ bí ẹ̀yin ó tí máa dá òlúkulùlku ènìyàn lóhùn.

Kólósè 4

Kólósè 4:2-7