Kólósè 4:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹyin olúwa, ẹ má a fi èyí tí ó tọ́ tí ó sì dọ́gba fún àwọn ọmọ-ọ̀dọ̀ yín; kí ẹ sì mọ̀ pé ẹ̀yin pẹ̀lú ni owa kan ní ọ̀run.

Kólósè 4

Kólósè 4:1-11