Kólósè 1:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sí èyí sì ni èmi ń ṣe làálàá, ti mo sì ń làkàkà pẹ̀lúgbogbo agbára rẹ̀, èyí tó ń sisẹ́ nínú mi.

Kólósè 1

Kólósè 1:24-29